Ọgbọ́n ló layé,

Yoruba26 lines2 public analyses
Original Poetry
Translation
Ọgbọ́n layé,
Wisdom is what rules the world,
Ìmọ̀ nílé ayé pẹ̀lú,
Knowledge is also the foundation of the world,
Ọgbọ́n la fi ń darí ohun gbogbo,
We use wisdom to guide everything,
Ọgbọ́n la fi ń ayé gbé pẹ̀lú,
We use wisdom to live in the world too,
Ẹni láyé lọ́gbọ́n lórí,
A person in the world without wisdom,
Irú wọn dàbí àpólà igi táa fi ń dáná,
Is like a piece of wood used for fire,
Àwọn yoòbá ọgbọ́n ju agbára lọ ó purọ́,
Those who say wisdom is greater than strength are lying,
Àwọn ọgbọ́n àti ìmọ̀ layé ò ṣèké,
Those with wisdom and knowledge own the world without deceit,
Torí bóò lọ́gbọ́n,
Because if you have wisdom,
bóo ṣe fẹ́ gbélé ayé,
You will surely live well in the world,
Ẹni ò lọ́gbọ́n á ṣebí òun lòun gbọ́n ,
Someone without wisdom will think they are the wisest,
Bẹ́ẹ̀ kòròfo òfo nirú wọ́n jẹ́,
But they are empty and void,
o lágbára, tóo lówó lọ́wọ́,
If you have strength and wealth,
Lálàì lọ́gbọ́n lórí, òfo ni gbogbo rẹ̀,
Without wisdom, it is all meaningless,
Torí bóò fọgbọ́n ṣe é,
Because if you do things with wisdom,
Àṣìlò òun òpin yóò gbogbo ohun o o jọ,
Misuse will bring an end to everything you have gathered,
Àmọ́ o ò lówó, o ò òkìkí,
But if you don't have wealth, nor fame,
Ṣùgbọ́n o lọ́gbọ́n,
Yet if you have wisdom,
pẹ́, bóyá, Akólòlò rẹ yóò pe baba,
In time, your wisdom will be recognized,
Báyé ń j'áyé,
As the world enjoys life,
Ọgbọ́n òun ìmọ̀ jogún ayé,
Wisdom and knowledge inherit the world,
Ọgbọ́n borí ohun gbogbo,
Wisdom conquers everything,
Ẹni ò lọ́gbọ́n kùnà làákàyè,
Someone without wisdom fails in understanding,
Ta fi ń gbélé ayé,
Which is used to live in the world,
Ẹni ó lọ́gbọ́n lórí,
Someone with wisdom,
Oun gbogbo pátá .
Has everything completely.
 

Explanation

This Yoruba poem underscores the paramount importance of wisdom and knowledge over material possessions and physical strength. It begins by asserting that wisdom is the guiding force of the world and is essential for navigating life. The poem draws a vivid comparison between those without wisdom to mere wood used for fire, emphasizing their lack of value. It critiques those who falsely claim that strength surpasses wisdom, highlighting that true ownership of the world comes from wisdom and knowledge. The poem warns that without wisdom, even the strongest and wealthiest are ultimately empty. It concludes by affirming that wisdom is the ultimate conqueror, and those who possess it truly own everything in life.

Word Dictionary89

WordIn YorubaIn EnglishPron.
Ọgbọ́nintelligenceWisdomOgbon
havehavelo
layéní ayéin the worldlaye
Ìmọ̀understandingKnowledgeImo
níléhomefoundationnile
ayéearthworldaye
pẹ̀lúwithtoopelu
daríleadguidedari
ohunthingthingsohun
gbogboeveryallgbogbo
ẸnipersonSomeoneEni
thatyouto
existiswa
nornorti
doesn'tnotko
lóríon toponlori
IrútypelikeIru
wọntheytheywon
dàbísimilarare likedabi
àpólàpartpieceapola
igitreewoodigi
táathat weusedtaa
fiuseis usedfi
ńisisn
dánácookfiredana
ÀwọntheyThoseAwon
yoòbásayclaimyooba
jumorethanju
agbárapowerstrengthagbara
lọgoislo
óitiso
purọ́falselyingpuro
àtiandandati
ṣèkéliedeceitseke
ToríbecauseBecauseTori
bóòififboo
noNoKo
havehavesi
ṣedodose
fẹ́wantwantfe
gbéléstaylivegbele
ṣebíassumethinksebi
òunitsitsoun
lòunareareloun
gbọ́nsmartwisegbon
moremostju
Bẹ́ẹ̀butYetBee
kòròfovoidemptykororo
òfonothingemptyofo
nirúsuchsuchniru
jẹ́areareje
ifIfBi
enjoysenjoysba
lágbárapowerfulstrengthlagbara
tóoandandtoo
lówómoneywealthlowo
lọ́wọ́handin handlowo
LálàìwithoutWithoutLalai
niisisni
rẹ̀ititre
fọgbọ́nwisdomwisdomf'ogbon
ÀṣìlòwastemisuseAsilo
òpinfinishendopin
yóòwillwillyoo
gathergatheredko
jọtogethertogetherjo
Àmọ́butButAmo
ififbi
ònotnoto
òkìkífamefameokiki
Ṣùgbọ́nbutYetSugbon
lọ́gbọ́nwisdomwisdomlogbon
ifEventuallyBo
pẹ́longlongpe
bóyámaybemaybeboya
AkólòlòwisdomwisdomAkololo
rẹyouryourre
pecallcallpe
babafatherfatherbaba
Báyéas the worldAs the worldBaye
j'áyélifelifejaye
jogúninheritinheritjogun
boríovercomeconquersbori
kùnàfailfailskuna
làákàyèwisdomunderstandinglaakaye
TathatWhichTa
OunownsOwnsOun
pátáallcompletelypata
hashasni

Poet & Context

Poet
EraUnknown

The poet of this Yoruba poem is unknown. Yoruba poetry is a rich tradition that often emphasizes wisdom and moral teachings.


WhenUnknown
WhyThe poem emphasizes the importance of wisdom and knowledge over material wealth and power. It reflects a common theme in Yoruba culture where wisdom is highly valued.
FormDidactic poetry

Themes & More

WisdomKnowledgeMaterialismLife Guidance
Metaphor: Comparing a person without wisdom to a piece of wood used for fire.Repetition: The word 'Ọgbọ́n' (wisdom) is repeated to emphasize its importance.Contrast: The poem contrasts wisdom with material wealth and strength.Personification: Wisdom is depicted as a guiding force capable of owning the world.